Ojo kejo osu karun-un odun 2013 ni Princess ati Adeshola Jeremiah ki owo bo iwe adehun lati je toko-taya. Sugbon o seni laaanu wi pe igbeyawo aladun naa pada di ikoro leyin osu keje ti won ti fe ara won sile.
"Ati igba taa ti fe ara wa ni a ti n ni gbonmisi-omi-o-to, a se boya ojuto yoo wa ni sugbon ko ri bee" Princess
"Nnkan bi osu melo kan seyin gan-an ni onikaluku ti lo lotooto, o kan je wi pe bonkele ni a fi oro naa se" Princess
Ode faaji to waye ni Muson Centre ni ilu Eko ni Princess ti pada jewo fun gbogbo araye.
Home / Amuludun /
Foto
/ Igbeyawo Princess (Omobirin Alawada) Ti Tuka Yangayanga Leyin Osu Meje Ti Won So Toko-Taya Papo
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment