
Mark 9:23
Fun awon ti o ba gbagbo, ohun gbogbo ni sise. Ko si ni si ohunkohun kankan ti won ko ni le se tabi ara ti won ko ni le da.
Igbagbo ni orisun ati opin ohun gbogbo.

Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
1/21/2014 09:56:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment