Smiley face

Ikunle Abiamo: Won Ti Ri Oku Omo Tuntun Ni Ilu Eko


Nibi ti enikan ti n sukun airibi, eni ti Edua fun lomo ju ti e danu. Oku omo tuntun yii ni awon kan ri ni agbegbe Ikorodu ni ilu Eko nibi ti won ti yimo aso pelu eje ati ibi omo (placenta).


Awon ti won kofiri isele naa so wi pe omo naa si wa laaye ti n mi nigba akoko ti awon eniyan kofiri re, sugbon o ba ni lokan je wi pe omo tuntun naa ku ki won to ri eni ti yoo ran omo naa lowo.


Omo naa ti ku. Omo tuntun ti pada sorun lojo to wa saye.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment