 |
| Mark Zuckerberg ati Jan Koum |
Sebi Onisango lorẹ Oníbàtá. Onibata si ni orẹ Onísàngó. Ile isẹ Facebook ti ra Whatsapp pa bayii pẹlu owo bi bilionu merindinlogun owo dọla ilẹ Amerika ($16b). Ọrọ yii ni alase ile ise Facebook, Mark Zuckerberg gbe jade nibi to ti n kede igbesẹ tuntun to waye naa. Gẹgẹ bi a se gbọ, alase ile ise Whatsapp, Jan Koum yoo dara pọ mo awon igbimọ ile ise Facebook lati maa ba ise rere naa lọ.
0 comments:
Post a Comment