Smiley face

Oníròyìn Ilé Isẹ́ NTA Jóná Mọ́lé


Oniroyin ile ise Iroyin NTA ti ilu Yola, Mallam Aliyu Zubairu ati iyawo re jona mọle ni oru ọjọ Aje to koja yii. 

Oga àgbà ati oludari ile ise NTA, Malam Adamu Yusuf si ti jeri gbe isẹlẹ naa wi pe lotitọ ni ina jo  Mallam Aliyu Zubairu ati ebi rẹ mọ ile wọn to wa ni Ijoba Ibile Yola-South ni deede ago kan oru ọjọ Aje to koja.

Won ti sin Mallam Aliyu Zubairu ni ilana Musulumi, a si gbo wi pe oniroyin naa ni i jabọ nipa ohun ti n sẹlẹ ni ile igbimọ asofin to wa ni ipinle naa.

Ki Olorun dẹ ilẹ fun ẹni to lo. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment