Smiley face

[Foto] Afihan Aworan Ojo Oni


Foto Kinni:
Oga ologun to padanu ese re mejeeji loju ija. Bi o tile padanu ese re, iyi ati ola re ko parun.
 Foto Keji:
Enikeni ti iwo ba ni ipa lati se iranlowo fun, oun naa ni enikeji re. Tooju re. Omobirin yii ran aro naa lowo nigba ti opolopo awon eniyan n sa fun ojo, omobirin naa duro lati se iranwo fun aro ti ko le rin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment