Enikeni ti iwo ba ni ipa lati se iranlowo fun, oun naa ni enikeji re. Too ju re.
Awon eniyan ti lo n fi eje sile fun awon eniyan ti won sagbako ninu ijamba ado oloro to waye ni ilu Abuja ni National Blood Transfusion Centre, Wuse 3, Abuja lati gba emi awon to wa lese-kan-aye ese-kan-orun sile.
Lara awon eniyan ti won gbe iru igbese yii ni asoju Ilu Biritiko ni ilu Nigeria (British High Commissioner to Nigeria) Dr. Andrew Pocock.
Home / Uncategories / Awon Omo Nigeria Rere Ti Lo N Fi Eje Sile Lati Ra Emi Awon Eniyan Ti Won Ko Ijamba Bombu Ti Won Wa Loju Iku
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment