Mo feran Yoruba fun kini kan soso, ko si ohun ti won ko ni alaye fun tabi asayan ede fun. Awon Yoruba ni were dun wo loja sugbon ko se e bi lomo. Bi o tile je wi pe titi di akoko yii enikeni ko ti le so idi pataki to mu Maheeda maa tu ara re si ihoho nita gbangba, sibesibe awon ololufe re si n so wi pe gbogbo bi ti n se pata ni n te awon lorun. A ti wi pe fiimu ofe ti n pate bi eleyii sowon lawujo wa.
Olayemi emi foro sinu, mo si n fi okan mi gbadura ki Edua oke sanu fun gbogbo wa.
Olayemi emi foro sinu, mo si n fi okan mi gbadura ki Edua oke sanu fun gbogbo wa.






0 comments:
Post a Comment