Smiley face

Ogun Oloro Heroin Lati Ilu Kenya Ti Bo Sowo Australia

Owo won omo ologun ori omi ti ilu Australia ti te oko oju omi to n ko ogun oloro(heroin) bo lati ilu Kenya.

Ogun oloro eleyii ti won ko sinu apo saka bi merindinlaadota (46) ni won ni iye owo re yoo to nnkan bi $290M.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment