Awon oniroyin amuludun agbaye ti so ninu iroyin won wi pe bi Rihanna to je onkorin ile Amerika ko tile korin mo, awon foto onihoho to fi n polowo oja fun awon magasiini agbaye lorisiirisii naa to jaye nitori owo kekere ko ni won gbe fun omobirin olorin ti won bi lodun 1988. Ile ise iwe iroyin magasiini kan ni ilu Faranse ni obirin yii ya gbogbo foto yii fun. Nje a le gba wi pe asa tuntun leyii bi?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)



0 comments:
Post a Comment