Smiley face

Ireti Ti Fe Pin Nipa Baalu MH370 Ti Ilu Malaysia To Sonu Loju Ofurufu

Olootu ilu Malaysia nigba kan ri Dr Mahathir Mohamad ti n siye meji boya lotito gan-an ni wi pe baalu MH370 jabo sinu omi okun.


Gege oro re, o ni bawo ni baalu to tobi bi MH370 se le jabo lai ma ri erunrun re lori omi.

Die lara oro baba naa ni yii:

"Can a plane that heavy, made of glass, aluminium, titanium and composites, plunge into the sea and not break up?"


"Even if the sea was calm, the plane must break up.

"But the suggestion is that the whole plane sank intact into the sea. Is this possible?

To date, nothing has been found to indicate the breakup of the plane."

Ojo kejo osu keta odun 2014 ni Baalu MH370 gbera lati Malaysia lo si China eleyii ti enikeni ko mo ibi to wole si doni. Awon eniyan bi igba ati mokandinlogoji lo si wa ninu baalu naa(ero:227, osise: 12).
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment