Sasa eniyan ni i feni leyin taa ba si nile, teru tomo ni i feni loju eni.
Awon Yoruba si ni ole nikan laaye o gba, ibi gbogbo lo gba alagbara.
Ilu Mexico ni King Wasiu Ayinde, Baba Yomade ti gbe n korin lowo. Gbogbo eniyan ni won si gba wi pe lotito oba fuji ko pe meji kari aye.
Orbit Entertainment lo se agbateru ariya naa. Bee si ni aimoye ilu ni won tun gbe K1 lo ni apa guusu agbegbe Amerika lagbaye.












0 comments:
Post a Comment