Ogbeni Rauf Aregbesola ti pada wole gege bi gomina Ipinle Osun pelu bo se bori ni awon ijoba ibile bi mejilelogun(22) ninu ogbon, nigba ti Senator Iyiola Omisore ko Ijoba Ibile mejo (8) to ku sapo tan patapata.
Apapo esi idibo:
Rauf Aregbesola (APC) : 203,090
Iyiola Omisore (PDP): 120,433
Fatai Akinbade (LP):18,135.
Nibayii, ajo INEC ti kede Ogbeni Rauf Aregbesola, erujeje Baba Kabiru gege bi olubori nibi eto idibo gomina Ipinle Osun to waye lojo Kesan-an osu kejo odun 2014.
Ki Olorun ko bukun ile NIGERIA!

Eko tiwa foju mumu han bayii, Aregbesola Baba K.b ride on....... Oga mi Olayemi E ku ise takun-takun Olorun a ma pelu yin o.
ReplyDelete