Smiley face

Oju Okunrin To Fe Dabi Micheal Jackson Ni Yii

Antonio Gleidson Rodrigues, eni odun mejilelogbon (32)  lati ilu Brazil lagbo wi pe o n lo acid pelu awon eroja kan lati so awo ara di funfun. Yato si eyi, aimoye owo lo tun na lori imu re ko le ri sosoro bi ti Micheal Jackson.

Amoran kan pere ni mo fe fun Antonio: bo ti n se bee ni o mo se lo. Ko maa lo bee.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment