Eniyan le seka ko binu ori. Eniyan si le seke ko fi enu dahe omolakeji. Sugbon otito oro ko lejanbakan ninu rara.
Emi ko ni mo so bee, awon ojogbon ni wo woye sakun bi nnkan se n lo lagbo amuludun ti won si fimo sokan wi pe toko-taya olorin to lagbara ju lagbaye ni Jay Z ati Beyonce ile Amerika.
Ilu France ni won ti de nibi won ti n korin kiri ti won pawo bi eni to gbe lukidi mi.
Tuntun ni wi pe awon toko-taya yii ti setan lati jumo gbe awo orin tuntun jade. Awo orin yii lo seese ko jade ni ibere odun 2015 tabi opin odun taa wa yii.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment