Smiley face

Awon Boko Haram Ti Yan Oba Tuntun Ti Yoo Maa Solori Gwoza Ni Ipinle Borno

Aye gba Tapa, o kole Igunnu. Awon Yoruba ni tobirin ba pe nile oko aje ni i da. Awon omo Boko Haran ti yan Oba Alaye tuntun ti o maa je ni agbegbe Gwoza ati Dambua to wa ni ipinle Borno leyin igba ti won ti je gaba si awon agbegbe yii.

E gbo ohun ti Senator Ali Dume to n soju Guusu Ipinle Borno nile igbimo asofin agba so fun awon omo ile ninu ipade won.


"I represent southern Borno and Gwoza.

The challenges we are facing are more serious than what we have faced before.

We, the people of southern Borno, particularly Gwoza, parts of Adamawa and Yobe know that it's presently occupied!

"I read here on the Senate Order
Paper about a threat.

It's no longer a threat; somebody is occupying that place and he's declared it a caliphate!

Yesterday, a new emir was installed by Boko Haram in Dambua.

The original emir is taking refuge in Abuja.

Boko Haram installed a new emir in Gwoza…

Recently, we conceded the extension of state of emergency and it was because it could get out of hand.

Can it get out of hand more than what is happening now?.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment