Egbe agbaboolu Nigeria, Super Eagles na akegbe won lati ile Congo mole pelu ayo meji si odo ninu ifesewonse taani-yoo-kopa ninu idije ifi eye ile Adulawo, AFCON ti o waye lodun to n bo.
Aseyori Super Eagles ti oni yii tun gbe ireti won ro nipa kikopa ninu idije AFCON eleyii to ku die ki won padanu latari aisedaada won ninu ifesewonse to waye tele.
Ikechukwu Uche ati Aaron Samuel ni omo egbe Super Eagle ti won gba ayo meji naa wole ti Congo ko si le ta putu loju awon ololufe won.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment