Smiley face

Jonathan Ti Lo Mule Pelu INEC Niwaju Ogun Lakaaye Oshimole - Asiwaju Bola Tinubu

Sebi eti oba nile, eti oba loko eniyan ni i je be. Okan lara awon oloye pataki lati inu egbe APC ti kede fun awon oniroyin wi pe, nibayii, Egbe PDP ati INEC ti jo mule di okan soso lati ja ijoba gba mo egbe APC lowo ni ilu Eko Oba Rilwan Akiolu omo Kutere.

Eniyan ti o puro ni o so wi pe eleri oun wa lorun, e gbo ohun ti Jagaban wi fun ra re:

"Just as we (APC) merged to form a
formidable opposition party, they(INEC) have merged with Jonathan to form a formidable rigging machine."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment