Smiley face

"O Puro Ni Awon Oloselu Wa" - Adeboye

Olori ijo Irapada Agbaye, Pasito E.A, Adeboye ti so fun awon oniroyin wi pe opuro ni awon oloselu ilu Nigeria ati wi pe gbogbo ileri won lori ofo ni.

Oro yii ni baba Adeboye so ninu ogba ile iwe Ifafiti Obafemi Awolowo to wa ni ile Ife nibi eto akanse adura kan to waye.


“I don’t trust politicians. Politicians are liars. They don’t fulfil most of their promises. A politician can tell you that they will give all of you (students) chicken each, which we all know it is impossible.” Adeboye
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment