Smiley face

Ina Jo Ni Ikorodu Emi Eniyan Sofo

Ti won ba n sadura 'Olorun ma je a rin lọjọ tebi n pọna", Amin nla lo ye koluwarẹ o se. Ni aarọ oni yii (17-03-15) ni agbegbe Ikorodu ni bireki tanka epo bẹntiro kan ti ja. Bi bireki se ja ni tanka naa dori ko Odo-ẹran ti n be ni agbegbe naa. Bi ina nla yii se bere si ni jo ni yii. Aimoye dukia lojo, aimoye eniyan lo si farapa pelu. Bakan naa la tun gbo wi pe enikan naa jona wuruwuru ninu ijamba ina buruku to waye naa.

Ki Edumare ba wa tu awon idile ti oro naa kan ninu. A o ni rin lojo tebi n pọna o. Amin  


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment