King Wasiu Ayinde Oba Fuji ti balẹ silu Dubai pelu awon irawọ osere onitia fun ayẹyẹ ọjọ ibi rẹ to ko laipe yii. King WASIU AYINDE TI PE OMO ODUN MEJIDINLOGOTA (58). Adura wa ni wi pe ko pẹ laye ninu owo ati alaafia. Amin.


Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
3/08/2015 06:14:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment