Smiley face

Kini Aishatu Se Ti Won Fi Gun Lọbẹ Pa?

Ika ni eniyan, odaju laye. Ki Edumare gba wa lowo eni ti n soni taamo. Osise ile ise telifisan Silverbird, Aishat Noble Mustapha ni awon amokunseka kan ti seku pa lale ojo Abameta to koja yii (14-03-15) ni nnkan bi ago mejo ale nigba ti orekelewa Oniroyin naa n pada bo lati ibi ise re.
Gege bi a se gbo, n se ni won fi obe gun omobirin naa nigbogbo ara re sakasaka.

Ibeere mi ni wi pe, ki ni ẹsẹ Aisha ti awon aye fi gun lọbe pa?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment