Smiley face

Omo Jide Kosoko Gbe Iyawo Lopin Ose To Koja

Okan ninu awon omokunrin omooba Jide Kosoko, Tunji Kosoko gbe iyawo ni opin ose to koja yii. Omo naa ko duro nile yii rara, ilu awon omo yibo lo ti lo re e mu aya wa le.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment