Wizkid Fi Ibadi Omoge Polowo Fila
Yato si ise orin, Ayo ti setan lati yasi sidi okoowo oge sise pelu bo se n pinnu lati se fila jade. Aworan yii lo gbe sori ero ayelukara pelu akole yii: "The Wizkid Hats almost ready to go live!"
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
3/18/2015 09:15:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment