Smiley face

Awon Foto Lati Ibi Ijamba Oko Ofurufu Awon Omo Ologun Niluu Kaduna

Awon aworan Oko ofurufu Dornier 228 ti awon omo ologun ile Nigeria ti a kede wi pe o jabo loju orun laaro oni ni yii. Awon eniyan meje ti won wa ninu oko ofurufu naa lo parun patapata.

E le ka iroyin naa nibi: bit.ly/1IsLJOG
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment