Smiley face

Foto Maanu Naa Ni Yii: Osise Arik Airline To Gbe Ogun-Oloro Wo Ilu London

Laipe yii ni a gbe iroyin okan ninu awon osise Arike Airline ti won ka ogun-oloro mo lowo niluu London. E le ka iroyin naa nibi:

www.olayemioniroyin.com/2015/08/osise-arik-airline-ba-naija-loju-je.html?m=1

Oruko maanu naa ni Chika Egwu-Udensi. Foto re si ni yii pelu ogun oloro to gbe wo ilu London.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment