Smiley face

Olatunbosun Oladapo Patan Ayo Leni Odun Mejilelaadorin (72)

Olatunbosun Oladapo
Ojo ibi baba tun ti wole de. Ki n maa paro, owo mi n gbon, mi o si mo ohun ti maa ko gan-an lati fi ki baba rere. Mi o tile mo iru agbekale asanyan oro ti mi o ba lo to le se aponle baba bi mo se fe gan-an lokan mi. 

Baba je eni to nifee, ti won si ko opolopo eniyan mora. Bi ohunkohun ba ru ni loju, ti e ba pe baba, suuru ati ayo ni baba fi n dahun. 

Adura mi ni wi pe ke e pe laye, ninu alaafia, ifokanbale, ogbon ati ilera to peye. 

Tope Falaanu ni ki n ki yin, Adewale Dada Thegood naa si fise ran mi. Won ni igba odun, odun kan ni. Ase


Olatunbosun Oladapo ti bere si ni se afihan awon aworan won aye atijo lati fi dupe lowo Oluwa fun irin-ajo odun mejilelaadorin ti won ti n ba bo lori erupe ile. Awon aworan naa ni yii nisale pelu awon akole baba:

21 01 1995
BALOGUN MAJEEOBAJE
NIILE IBADAN TILE TOKO

E BA WA GBOMO OKEEE....LANTI LANTIII

OMO OKE DUN UN BI
BI A BI I LONII A RIN LOLAAA\

 IRE OOO



 BALOGUN MAJEEOBAJE TILE IBADAN
NINU OSU AKOKO ODUN 1995
ALAYELUWA OBA
EMMANUEL.ADEYEMO OPERINDE AKOKO
OGUN ODUN REKOJA LO
BI ANA LO RI
BI ALA LO RI
AYO NI OOO

E BA WA GBOMO OKE.....

OMO OKE DUNUN BI.....
AYO NI OOO
IREEE

 

 NINU OSU KEJO ODUN 1986
OLATUBOSUN DI AARE ONIRE
TI ILU IRE EKITI
OBA ADEYEYE LO N SE ADURA FUN AARE
ABA RE AA GBE E
HIN OOKUN OOO

 

 OLATUBOSUN NIYEN LODUN 1965
GEGE BI OLORI AWON AKEKOO
CLASS CAPTAIN NI SCIENCE CLASS IA
ST LUKES TEACHER TRAINING COLLEGE
OKE MOLETE IBADAN
AADOTA ODUN KOJA LO
BI ANA LO RI
BI ALA LO RI
OPE...IYIN...OGO..
NI FUN ADEDAA ASEDA OBA OLODUMAREEE
AYO NI OOO
IRE NI FUN EYIN NAA PAPAA
IRE KABITIII



ODUN 1954 LEYI OOO
NILE EKO ALAKOOBERE
CANON OKUSEINDE MEMORIAL PRY.SCHOOL
AREMO ILU IBADAN
OLATUBOSUN KEKERE LE N WO YEN
ENI TO JOKOLE SIKETA LATI APA OSI
OUN LO FI SOOKI EFUN LA PATIN
SI AARIN ORI..

BI ALA LO RI
BI ANA LO RI
OMO KEKERE OJO YEN
O TI DI BABA BABA BABA...
PAPA70+
E YIN OLUWA LOGO OOO
EYIN NAA YIO PITAN RERE
LAGBARA OLODUMARE
AYO NI OOO
IREEE



BI ANA LO RI LODUN1958
NI ISLAMIC SECONDARY MODERN SCHOOL
AGUGU IBADAN
OLATUBOSUN KEKERE LE N WO YEN
TO JOKO SIKETA LAPA OTUN
OLUWA O SEUN OOO
OMODE OJOSI TI DI PAPA72+
AYO NI OOO
EYIN NAA YIO DAGBA OPITAN RERE
IRE OOO



TISA OKO..OLATUBOSUN OLADAPO
LASIKO OMINIRA NIGERIA 1960.
.
EYIN TI ABA OBA ARAROMI OWU AYEDAADE
E KU ATIJOTIJO OOO

TISA KEKERE OJOSI
TI DI BABA AGBA PAPA7O+....
.
OPE OPEE OPEEE


Ninu iroyin mii:

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment