Smiley face

"Mi o gba riba ri laye mi". - Rotimi Amaechi

Gomina ipinle Rivers nigba kan ri, Ogbeni Rotimi Amaechi, so niwaju ile igbimo asofin agba lonii wi pe oun o gba riba ri laye oun.

Nje e gba wi pe oseese fun oloselu kan nile Naijiria lati ma lowo ninu riba ri?

#YorubaDun
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment