Smiley face

Adanwo ni oro ile aye: Iku Abubakar Audu gba arojinle

Titi di akoko yii, enikeni ko le so pato ohun to sekupa oludije ipo gomina labe egbe oselu APC ni ipinle Kogi, Abubakar Audu. Se ise aye ni abi amuwa Olorun oba? Ohun ti ko ye enikan, kedere ni niwaju Olorun Oba. 
Olayemi Oniroyin, joojumo ni mo n kogbon aye. Gbogbo igba ni mo si n ran ara mi leti wi pe asan ni duniyan, omulemofo nigbogbo re pata je. 

Sugbon adura kan lo wu mi ti mo fe se fun gbogbo eyin ololufe Olayemi Oniroyin, ojo ti ire ayo yin ba wole de, imo esu ko ni ba ayo naa je. Odun n lo sopin, ibanuje, o kere, o tobi, ko ni wo ile wa. A ko ni rogun ekun, idaamu, wahala, ipayinkeke ko ni yale enikeni wa. Amin.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment