Smiley face

Ona ti e le gba ti ayeye yin yoo fi larinrin niyii

Aye igba kan lo je wi pe awon olobirin ile ni won ma pin ounje fun awon alejo loju agbo. Oju ni won fi n pin ounje. Ti won ba gbe ounje fun Iya Kabiru, won o ni gbe ounje de odo Iya Shola. Won le ni ko ra ankara lo je ki awon gbe ounje koja re. Sugbon ki lodun bi ki eniyan ni alase olori pipe, ti won se aponle awon alejo bi oba.

Ipapanu ni won fi n pade awon alejo lona. Bee ni won ki won kaabo sagbo ariya pelu oyaya.  
Lati ibe ni awon alejo yoo ti maa bo sinu gbongan nla, eleyii ti won ti se lojo kale pelu orisiirisii arambara oge ti n danilorun bi paradise.
E so fun mi na, iru ounje wo gan-an leyin fe?
E ma je ki n paro fun yin, ti iru ayeye bayii ba wu yin, Chrisyetty Catering Service ni awon alariya n foro lo. Ko wa si ohun te e ni ki won se, ti won ko le da lara. Sebi Edumare lo se ori ewa fakuko. Okin loba eye, eni te e ba ri ke e bi. Chrisyetty Catering Service loga nla ninu ka gbe ariya kale lai labuku.
Chrisyetty Catering Service
2, Joy Road, Redemption Camp, Ogun State .
07069304313, 08068918730
chrisyetty@yahoo.com

 E pe won lonii, o daju wi pe e o pada dupe lowo Olayemi Oniroyin bo dola ni. Ire o!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment