Smiley face

Kini ero yin nipa awon obirin to ga fiofio?

Mo mo wi pe awon obirin maa n fe lati fe awon okunrin to ba ga. Sugbon mi o mo boya bakan naa lori pelu awon okunrin nipa fiferan awon obirin to ga fiofio.

Se kii se wi pe giga obirin le mu awon okunrin maa sa fun?

YORUBA DUN
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment