Smiley face

Pataki ede Yoruba - Prof. Sophie Oluwole

 

Kin ni won pe ni ojulowo imo?

Se lotito ni awon eniyan dudu kii se atunse imo ati ogbon won?

Se fanakula ni Yoruba looto?

Kin ni pataki siso ede Yoruba?


Se ede awon oloju dudu ni Yoruba looto?

Awon kan ni Geesi dara ju Yoruba lo, kin ni Ojogbon so nipa re?

Gbogbo alaye wa lenu Ojogbon  Sophie Oluwole. E tun le je igbadun imo to ku lori telifisan Tunde Kelani.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment