Smiley face

"Sukura, akobi K1 loyun fagbero"- ALARIYA OODUA lo so bee

Lati inu iwe Iroyin Alariya Oodua ni iroyin yii ti jade wi pe, akobi omobirin Wasiu Ayinde ti gboyun lowo agbero onimoto kan ni agbegbe Ketu.

Won ni ile iya Wasiu to wa ni Ketu ni Sukura n gbe, ati wi pe ko loko.

Koda, iwe iroyin Alariya so wi pe o seese ki K1 ko o lomo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment