Smiley face

Won ti ri omoge ti won gbe pamo sinu ajaale fosu mejo

Arabirin orekelewa yii ni awon ika eniyan gbe pamo sinu ajaale fun odindi osu mejo. Eemeji ni won fun obirin naa ni ounje ninu ose kan.



Igba ti asiri yoo pada tu, oko afesona re ni won ba nidi ise ibi naa, eni to n gbiyanju lati di olowo ojiji.

Obirin naa ko ti i ku, emi si wa lara re.
Orileede Tanzania ni isele naa ti waye, ori gbogbo wa ko ni gbabode. Amin


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment