Smiley face

IROYIN OWURO ose yii kun fofo bi ataare

 OGUN 2019: Tinubu, Yayi setan
ati ba Amosun fa surutu
* Aarin Asiwaju ati Amosun ko dan moran mo
* Gbenga Daniel fe faramo Tinubu


Ambode si oja Mile 12,
o fe so TBS di budo igbafe
* Ijoba Eko ati Ogun n 'ja' si awon oloja Ketu


Ile ejo ni Saraki fi owo ijoba san gbese ara re

Awuyewuye be sile
laarin Fayose ati
awon oga ile iwe
aladaani Ekiti


Adari bi oloogbe Abacha ni Naijiria nilo - Omo Aje orun

Ni Ado Odo Ota, awon Baale
n binu si Amosun!

Esuke wo rara nipinle Osun:
Milionu mefa naira pere nijoba
apapo fun un losu yii
* Paa-hee gba okan awon osie

Molebi oga onifiimu ti won
dajo ewon fun n rawo ebe

Emir Ilorin gba IROYIN OWURO lalejo

Ese ko gbero nibi igbeyawo Ooni Ogunwusi


Bukky Wright
jeun soke pelu
Elkris Super Oat

Awon osere gbosuba fun Joke Muyiwa
IROYIN OWURO ose yii kun fofo bi ataare...   E gbiyanju ke e ni ti yin lowo. Ogorun naira pere.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment