Smiley face

Switzerland da N142b pada ninu owo t’Abacha jiko pamo



Sani Abacha
Ijoba ile Switzerland ti kede wi pe, ogorun meje ati metalelogun milionu owo dola ilu Amerika ($723m eleyii to n lo bi N142.43b) ti aare ologun ile Naijiria nigba kan, oloogbe Sani Abacha ko pamo siluu won ni won ti dapada fun ile Naijiria lati nnkan bi odun mewaa seyin.  Eleyii lo fojuhan ninu iwe adehun ti ile Naijiria ati Switzerland fowo si lojo kejo osu keta odun yii (8-03-16).


Yato si eleyii, ijoba ile Switzerland tun fi kun un wi pe, awon yoo tun da ogorun meta ati okanlelogun milionu owo dola ($321m eleyii to n lo bi N63.24b) pada laipe yii. Gbogbo eleyii lo pelu adehun ti orileede mejeeji se eleyii ti Minisita fun eto idajo ile wa, Abubakar Malami, buwo lu pelu olori eka ile ise ijoba ile Switzerland ti n ri si oro okeere, Didier Burkhalter.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment