Smiley face

Agbara Olorun fara han laaarin omi okun

Alagbara ni Olorun oga ogo. Ogangan ibi ni odo Mississippi ati Gulf of Mexico ti pade. Omi odo kan pon, ekeji si funfun. Bakan naa ni awon mejeeji ko dapo mo ara won ri. Bi won se wa ni yii lati ojo ti Edumare ti da won saye. Nje enikan si wa to gba wi pe ko si Olorun bi?


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment