Smiley face

Aye akamara: Won dana sun Lawal latoju orun

Muhammed Lawal

Ogbeni Muhammed Lawal ni enikan ti da epo eebo lu lara ti won si sana si i. Lojiji ni gbogbo ara okunrin naa gbana, ti gbogbo re si n jo bulabula bi igba ti won sun eran ileya.
Gege bi alaye Ogbeni Lawal, o ni apoju oru lai si ina monamona lati tan faanu lo mu ohun sun sita ile oun tori ategun. “Lati oju orun ti mo wa ni mo ti se akiyesi wi pe, enikan an da epo eebo si mi lara. Ki n to  mo ohun ti n sele, ina ti dahun lara mi,” Lawal se alaye bee fun awon oniroyin.
 

Ipinle Kastina ni isele yii ti waye. Ogbeni Lawal si ti wa ni Lawan Katsina General Hospital bayii nibi to ti n gba itoju. Taa wa ni Lawal se? Taani amokunseka to fe ran Lawal sorun loru oganjo? Iwadii awon olopaa si n lo lowo lati mo wulewule oro naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment