Smiley face

Kilode ti won fi obirin yii se yeye?

Gbogbo ohun ti Olorun da, daradara ni. Ki lo wa de ti eda eniyan fi n fi eya ara eda elomii se yeye. Eleyii buru jai. Omobirin naa ko tile binu, erin ni i fi won rin pelu bi won se pe le e lori ti won fi n se yeye.

Baba darijin won...

 
Eni to kan si wa se alaye wi pe, agbegbe Ikeja niluu Eko ni isele naa ti gbe waye
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment