Smiley face

Ẹni ba laya ko maa bọ lojude: Ere idaraya ibilẹ Yoruba

Demilola Abass
Ere idaraya jẹ ọkan pataki ninu asa Yoruba eleyii ti awon Yoruba ma n se nigba ti ọwọ ba dilẹ. Ere idaraya ko si wa fun awon ọmọde nikan, àgbà naa pẹlu. O kan jẹ wi pe, oun ti awon agba fi n dara won ninudun yato si tọmọde.



E je ka wo baya eyin le dahun ibeere Demilola Abass, to jẹ sọrọsọrọ ori fẹfẹ.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: