Smiley face

Lekan Shonde wọ gau! Won ti n gbe lọ silẹ ẹjọ fun esun apaniyan

Leyin gbogbo rukerudo to ti n waye leyin iku Ronke Shonde ti won ni oko re seku pa, nibayii, ile ise olopaa ile yii ti setan lati gbe Lekan Shonde lo si ile ejo pelu esun apaniyan.

Ninu atejise ti alarina ileese olopaa ipinle Eko,  Dolapo Badmos, fi ranse si awon oniroyin lo ti n wi pe,

“The autopsy has revealed that Mr. Lekan Shonde, the alleged killer of his wife has case to answer. Therefore he will be charged to court tomorrow (Friday) to answer a charge of murder.”

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment