Smiley face

Ona lati gbogun ti aisan jẹjẹrẹ ati awon kokoro ara to ku

Aimoye iwosan ni eniyan le fi ewe Ebo tabi Apekan (Graviola or Soursop) se. Eleyii ti awon kan ti se iwadii re ti won si ba bee. Lara awon ohun ti eniyan le fi ewe yii se ni lati gbogun ti aisan jejere ati awon kokoro mi i ti n ba ara eniyan ja. E kunrere alaye ni yii nisale.



 Orisun: www.healthadvisorusa.com


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment