Smiley face

Oniroyin TVC ti kanjangbọn: O na ololufẹ rẹ daran

Osise ileese mohunmaworan TVC, Wale Fakile, ti na  afesona re daran bayii. Ohun ti a gbo ni wi pe, awon olopaa ti gbe okunrin naa leyin ti obirin to na gbe aworan apa ara re sori FACEBOOK.

 “I am Mandy, my supposed boyfriend that works with TVC, beat me yesterday to stupor with bruises all over and he said there is nothing I can do about it bcos he is rich and works with TVC and am poor." Mandy afesona re lo ko eleyii sori FACEBOOK.

Ile ise TVC naa ti bere iwadii isele naa lati mo okodoro oro naa.




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment