Smiley face

Se eyin ri iru gele bayii ri?

Onigele yii...

Imura omobirin Yoruba atata ko ti pe lai si gele lori. Orisiirisii oge ni awon eniyan si n fi gele dalara lati mu gbayi loju. Bi o tile je wi pe orisiirsii gele wiwe ni mo ti ri, eleyii tun kasiara.

Nje iru oruko wo ni a le fun iru sitayi gele wiwe yii?

E ka ohun ti awon eniyan n so nipa gele naa NIBI 

https://www.facebook.com/photo.php?fbid=267010243650970&set=gm.1194857113898929&type=3&theater
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment