Smiley face

Tani awon eniyan ni ki won dajo iku fun?

https://www.facebook.com/photo.php?fbid=271261749892486&set=gm.1200201050031202&type=3&theater
Awon ilu okeere kan ti n pete-pero lati sofin idajo iku fun awon ti won fi tipatipa ba awon omode lajosepo. Bakan naa ni apero kan tun waye lori koko oro yii lojo ayajo awon ewe agbaye. Nje eyin fe ki iru ofin yii naa wa ni Naijiria?

Ero awon eniyan wa nibi
https://www.facebook.com/photo.php?fbid=271261749892486&set=gm.1200201050031202&type=3&theater

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment