Smiley face

Total Experience 2016: Agbara emi mimo ati ogo

Total Experience 2016
Bibeli so wi pe, ami wonyii ni yoo ma tele awon to ba gbamigbo: ni oruko mi ni won yoo ma le emi okunkun jade... Mark 16:17

Ipade nla Total Experience ti ijo Christ Embassy yoo ma waye lojo ketadinlogbon osu karun-un odun yii [27-05-2016] ni papa Tafawa Balewa Square to wa niluu Eko gomina Ambode.

Kosi iye meji, agbara Olorun oga ogo yoo so kale, awon eniyan yoo si gba imularada. Opo awon eniyan ni ilekun ijoba orun yoo si sile fun lati di atunbi. Afoju yoo riran, awon aro yoo si fo fayo.
Onibinuje yoo si di alayo repete. Wa, iwo yoo si ri ogo Olorun.

E ma gbagbe, Jesu ni Oluwa!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment