Smiley face

Yegede! Won ti sawari epo robi nipinle Eko Ambode

Ori ire ti wọ ilu Eko pelu bi ile ise Yinka Folawiyo Petroleum Company Limited se se awari epo robi ni agbegbe Badagry to wa ni ipinle Eko. Ohun ayo tuntun yii ti mu ipinle Eko naa wa lara awon ipinle ti won yoo ti ma wa epo robi ti n pawo bi kalokalo fun Naijiria.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment