Smiley face

Alaaja se ololufẹ rẹ loge labẹẹle

Awon gbeborun kan ni won kofiri obirin yii nibi o ti n ba ọkọ rẹ gerun. Awon kan ni oseese ko jẹ ọrọ aje Naija lo mu onikaluku ma dọgbọn si labẹẹle. 
 
Sugbon ka ma parọ, Alaaja yii mọrun ge gan-an ni sa, a bi ẹ ri bo se mu kilipa dani ni?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment