Smiley face

E wa wo ohun ti won se fun Ooni Ojaja nigba to fe mu omi niluu Amerika

 Awon aworan Ooni Ogunwusi niyii ni Library of CONGRESS, nibi won ti da lola pelu ami-eye.

Sugbon nigba ti baba fe gbe nnkan senu, won ni eewo ni, enikeni ko gbodo ri Ooni nibi to ti n jeun tabi mu omi.


Orisun foto: Tunde Alabi
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment