Smiley face

Eto igbeyawo eleyii tun sara ọtọ

Lara eto igbeyawo naa ni o. Iyawo sebi eni to daku, won si gbe sinu moto ti won fi n gbe awon alaisan. Igba ti won gbe debi tọkọ rẹ wa to fẹnu ko o lẹnu ni iyawo ba ji dide bi oku Lasaru ojo kẹta. Erkk

Ko si ohun ti awon eniyan ko ni da lara tan. 

Eniwee, eyin iyawo ko ni meni o! 

Ẹ si ba wa kilọ fun iyawo, ko ye ma fi modaku sere o.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment